ioruba,+yoruba,+nago,+lukumi,+orisha+prayer

NEW MONTH IFA PRAYER (APRIL 2019)

Erin ja, erin won loluso
Agbo momo ja, won mu so loja ejigboromekun
Adifa fun orisa nla Oseremagbo
Ni ojo ti iku yio gbodo ti yio si ma pani
Erin ja, erin won loluso
Agbo mo mo ja, won mu so loja ejigboromekun
Adifa fun Orunmila ti yio je oni magba, to yio si ma gba ni Kaye.
Nje ki lo to ni gba nijo ogun
Erigi alo ifa lo to ni gba lojo ogun
Erigi alo

Translation :
The elephant escaped been tie down with rope
The ram was been tied at the market of ejigboromekun
Cast divination for orisa nla oseremagbo
When death will dominate everywhere and taken lives
The elephant escaped been tied with rope.
The ram was been tied at the market of ejigboromokun
Cast divination for orunmila when he will became the messiah on earth and keep saving life
What is it that can safe us during spiritual war.
Erigi alo, it is IFA that can safe us.
Erigi alo…(EJIOGBE)
As we embark on the journey of this new month of April, May Olodumare grant us success in all our endeavors and may our ori, IFA olokun Asorodayo guide our path to success. Ase’ntedumare

From: Ancestral pride temple, Ota
Oluwo Fasola Faniyi