AncestralPride_orishaCalendar

IFA/ORISA MAY CALENDAR (2017)

1. Ogun/Osoosi/Orisa Oko

2.  Sango/Oya

3.  Obatala/Egungun/Iyaami/Sanpanna

4.  Ifa/Esu/Osun/Aje/Yemoja/Olokun

5.  Ogun/Osoosi/Orisa Oko

6.  Sango/Oya

7.  Obatala/Egungun/Iyaami/Sanpanna

8.  Ifa/Esu/Osun/Aje/Yemoja/Olokun           **

9.  Ogun/Osoosi/Orisa Oko

10.  Sango/Oya

11.  Obatala/Egungun/Iyaami/Sanpanna

12.  Ifa/Esu/Osun/Aje/Yemoja/Olokun

13.  Ogun/Osoosi/Orisa Oko

14.  Sango/Oya

15.  Obatala/Egungun/Iyaami/Sanpanna

16.  Ifa/Esu/Osun/Aje/Yemoja/Olokun

17.  Ogun/Osoosi/Orisa OkoContinue reading

OBARA IRETE

THIS YEAR 2016 IFA READING/MESSAGES OF ODU IFA OBARA IRETE FROM THE STABLE OF ANCESTRAL PRIDE TEMPLE LIMITED IN CONJUNCTION WITH ORUNMILA BROTHERHOOD FOUNDATION FOR THE ANNUAL WORLD IFA FESTIVAL HELD IN OKE ITASE ILE IFE NIGERIA,JUNE 2016 ……ELABORU , ELABOYE , ELABOSISE.

1.Amoran oloran ma mo tara re adifa fun olobara ti yio dete ni gongo imu o n ti kole orun bo waye ,won ni o kara nle ebo ni ko ma se, koipe keijina e wo ifa awo ki bo ti se.

Ebo; ifa ni eyele ni ebo,Ohun ti ifa so ni wipe ki onikaluku ma ran ti ara e,ki a ma se ma se ayonu so tabi ayojuran si oro oloro tabi oro ti ko kan wa nitori ka ma ba ko arun buruku tabi ka ma ba fi ori gbe oun buruku ti ki se tiwa.

Translation;
He who shows concern or prognose into others people affairs and does not mind his/her own affairs cast divination for olobara when he was going to posses leprosy at the forefront of his nose,he was ask to make ebo,thus sooner or later the words of ifa came to reality.
Offering; ifa said we should offer some pigeon here
Ifa is telling each and everyone of us to be mindful of our own issue and stop interferring into someone else’s affairs so that we will not be affected with bad diseases that is not meant to happen to us.

2.Obara rete rete awo ate lodifa fun ate ,ate n lo si oja ejigboromekun won ni o kara n le ebo aje ,ebo ire gbogbo ni won ni ko se.

Ebo; ifa ni ki a fi eyele merin rubo ,ki a si wa nkan ti aje ba gba ka fi bo aje nitori ire aje,ifa ni opolopo yio rin irin ajo ninu odun yi ,ki a le ko ire bo irin a jo naa ati wipe ki awon sowo sowo ki won le jere lopolopo.

Translation;
Obara rete rete awo ate ( ate is a tray use to exhibits good and product at the market) cast divination for ate when he was embarking on a journey to the market of ejigboromekun (acient market of ejigboromekun),he was ask to make ebo for good fortune.
Ifa ask us to make offering to esu odara with four pigeon and also make offering to aje olokun (orisa of wealth) beause of general fortune,ifa said many awo and traditionalist will embark on a business trip this year and shall return with good fortune,and that all business will function well this year.

3.Ebo riru ni fi moju iku, eru tutu ni fi ba arun mule adifa fun olobara to n lo re roko ahoro won ni o kara nle ebo ni ko se, nje ki ni olobara ro dete oko ahoro ni olobara ro dete ,oko ahoro.

Ebo;ifa ni ki a fi ewure rubo ,ki a si tun fi ewure bo ifa ni okan ti be ,ki a si ma lo si oko lati lo ro oko nitori ki a ma ba ko arun .
Olobara lo lore dafa won ni ki o rubo ,ko si ma lo si oko,sugbon olobara ko gbo ikilo ti ifa so fun ,o gba ona oko lo nigbati ti o de ohun ni o ba roko dete ,ni wo ba ko le fun ni ohun nitori adete ki gbe arin ilu….ifa ni ki a sora lati ma lo si ona oko lodun yi

Translation;
Sacrifice is use to appease daeth,offering is use to make oath with diseases cast divination for olobara when he was embarking on a shallow farming he was ask to make ebo and not to go,thus what make olobara a leprotic .it was a shallow cutting/farming that makes olobara a leprotic.
Ifa ask us to make use of she goat as offering and also offer another she goats for ifa, and importantly we should be caeful of going on farming,or probably going to family farmland we have left for longtime this year.Continue reading